Jeremaya 51:13 BM

13 Ìwọ Babiloni, tí odò yí ká,tí ìṣúra rẹ pọ̀ lọpọlọpọ,òpin ti dé bá ọ,okùn tí ó so ayé rẹ rọ̀ ti já.

Ka pipe ipin Jeremaya 51

Wo Jeremaya 51:13 ni o tọ