Jeremaya 8:3 BM

3 Yóo sàn kí àwọn tí ó bá kù ninu ìran burúkú yìí kú ju kí wọ́n wà láàyè lọ, ní ibikíbi tí mo bá lé wọn lọ. Èmi OLUWA àwọn ọmọ ogun ni mo sọ bẹ́ẹ̀.”

Ka pipe ipin Jeremaya 8

Wo Jeremaya 8:3 ni o tọ