Jeremáyà 1:5 BMY

5 Kí ó tó di pé mo dá ọ láti inú ni mo ti mọ̀ ọ́,kí ó sì tó di pé a bí ọ ni mo ti yà ọ́ sọ́tọ̀.Mo yàn ọ́ gẹ́gẹ́ bí wòlíì fún àwọn orílẹ̀ èdè.

Ka pipe ipin Jeremáyà 1

Wo Jeremáyà 1:5 ni o tọ