Jeremáyà 10:13 BMY

13 Nígbà tí ó bá sán àrá, àwọn omilọ́run a sì pariwo, ó mú kí ìkuùkù rusókè láti òpin ayé: ó rán mọ̀nàmọ́ná pẹ̀lú òjò,ó sì ń mú afẹ́fẹ́ wá láti ilé ìṣúra rẹ̀.

Ka pipe ipin Jeremáyà 10

Wo Jeremáyà 10:13 ni o tọ