Jeremáyà 11:19 BMY

19 Mo ti dàbí ọ̀dọ́ àgùntàn jẹ́ẹ́jẹ́ tí a mú lọ fún pípa; N kò mọ̀ pé wọ́n ti gbìmọ̀ búburú sí mi wí pé:“Jẹ́ kí a run igi àti èso rẹ̀;jẹ́ kí a gé e kúrò ní orí ilẹ̀ alààyè,kí a mọ́ lè rántí orúkọ rẹ̀ mọ́.”

Ka pipe ipin Jeremáyà 11

Wo Jeremáyà 11:19 ni o tọ