Jeremáyà 12:15 BMY

15 Ṣùgbọ́n tí mo bá fà wọ́n tu tán, Èmi yóò padà yọ́nú sí wọn. Èmi yóò sì padà fún oníkálùkù ní ogún ìní rẹ̀ pẹ̀lú ilẹ̀ ìní oníkálùkù.

Ka pipe ipin Jeremáyà 12

Wo Jeremáyà 12:15 ni o tọ