Jeremáyà 13:27 BMY

27 ìwà àgbèrè àti ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́,àìlójútì aṣẹ́wó rẹ!Mo ti rí ìwà ìkórìíra rẹlórí òkè àti ní pápá.Ègbé ni fún ọ ìwọ Jérúsálẹ́mù!Yóò ti pẹ́ tó tí o ó fi máa wà ní àìmọ́?”

Ka pipe ipin Jeremáyà 13

Wo Jeremáyà 13:27 ni o tọ