Jeremáyà 15:3 BMY

3 “Èmi yóò rán oríṣìí ìparun mẹ́rin láti kọlù wọ́n,” ni Olúwa wí, “Idà láti pa, àwọn ajá láti wọ́ wọn lọ, àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run àti àwọn ẹranko orí ilẹ̀ láti jẹ àti láti parun.

Ka pipe ipin Jeremáyà 15

Wo Jeremáyà 15:3 ni o tọ