Jeremáyà 16:19 BMY

19 Olúwa, alágbára àti okun miẹni ààbò mi ní ọjọ́ ìpọ́njúÁà! àwọn orílẹ̀ èdè yóò wá látiòpin ayé wí pé,“Àwọn baba ńlá wa kò ní ohunkan bí kò ṣe ẹ̀gbin òrìsà,ìríra tí kò dára fún wọn nínú rẹ̀.

Ka pipe ipin Jeremáyà 16

Wo Jeremáyà 16:19 ni o tọ