Jeremáyà 16:6 BMY

6 “Àti ẹni ńlá àti kékeré ni yóò ṣègbé ní ilẹ̀ yìí, wọn kò ní sin wọ́n tàbí sọ̀fọ̀ wọn, bẹ́ẹ̀ ni kò sí ẹni tí yóò fá irun orí wọn nítorí wọn.

Ka pipe ipin Jeremáyà 16

Wo Jeremáyà 16:6 ni o tọ