Jeremáyà 2:2 BMY

2 “Lọ kéde sí etí ìgbọ́ àwọn Jérúsálẹ́mù:“ ‘Mo rántí ìfarasìn ìgbà èwe rẹ,gẹ́gẹ́ bí o ṣe nífẹ̀ẹ́ mi bí i wúndíá àti bí o ṣe tẹ̀lé mi nínú aṣálẹ̀ àti nínú ìyàngbẹ ilẹ̀.

Ka pipe ipin Jeremáyà 2

Wo Jeremáyà 2:2 ni o tọ