Jeremáyà 20:15 BMY

15 Ègbé ni fún ọkùnrin tí ó mú ìròyìn wá fún baba mi,Tí ó mú kí ó yọ̀, tí ó sì sọ wí pé,“A bí ọmọ kan fún ọ—ọmọkùnrin!”

Ka pipe ipin Jeremáyà 20

Wo Jeremáyà 20:15 ni o tọ