Jeremáyà 20:5 BMY

5 Èmi yóò jọ̀wọ́ gbogbo ọrọ̀ inú ìlú yìí fún ọ̀ta wọn. Gbogbo ìní wọ́n gbogbo ọlá Ọba Júdà. Wọn yóò sì ru ìkógun lọ sí Bábílónì.

Ka pipe ipin Jeremáyà 20

Wo Jeremáyà 20:5 ni o tọ