Jeremáyà 20:8 BMY

8 Nígbàkúgbà tí mo bá sọ̀rọ̀, èmi sì kígbe sítaèmi á sọ nípa ipá àti ìparun.Nítorí náà, ọ̀rọ̀ Olúwa ti mú àbùkùàti ẹ̀gàn bá mi ni gbogbo ìgbà.

Ka pipe ipin Jeremáyà 20

Wo Jeremáyà 20:8 ni o tọ