Jeremáyà 21:1 BMY

1 Ọ̀rọ̀ Olúwa sì tọ Jeremáyà wá nígbà tí Ọba Sedekáyà rán Páṣúrì ọmọ Málíkíjà àti àlùfáà Sedekáyà ọmọ Mánásè síi; wọ́n wí pé:

Ka pipe ipin Jeremáyà 21

Wo Jeremáyà 21:1 ni o tọ