Jeremáyà 21:6 BMY

6 Èmi yóò sì lu gbogbo ìlú yìí, ènìyàn àti ẹranko, gbogbo wọn ni àjàkálẹ̀-àrùn yóò kọlù tí wọn yóò sì kú.

Ka pipe ipin Jeremáyà 21

Wo Jeremáyà 21:6 ni o tọ