Jeremáyà 21:8 BMY

8 “Síwájú síi, sọ fún àwọn ènìyàn, ‘Èyí ni ọ̀rọ̀ Olúwa tí ó sọ: Wò ó, Èmi ń fi ọ̀nà ìyè àti ikú hàn yín.

Ka pipe ipin Jeremáyà 21

Wo Jeremáyà 21:8 ni o tọ