Jeremáyà 25:4 BMY

4 Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé Olúwa ti rán gbogbo àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀, àwọn wòlíì sí i yín láti ìgbà dé ìgbà, ẹ̀yin kò fetí sílẹ̀.

Ka pipe ipin Jeremáyà 25

Wo Jeremáyà 25:4 ni o tọ