Jeremáyà 26:21 BMY

21 Nígbà tí Ọba Jéhóíákímù àti gbogbo àwọn aláṣẹ gbọ́ gbogbo ọ̀rọ̀ rẹ̀, Ọba ń wá láti pa á: ṣùgbọ́n Úráyà gbọ́ èyí, ẹ̀rù bà á, ó sì sálọ sí Éjíbítì.

Ka pipe ipin Jeremáyà 26

Wo Jeremáyà 26:21 ni o tọ