Jeremáyà 26:8 BMY

8 Ṣùgbọ́n ní kété tí Jeremáyà ti parí ọ̀rọ̀ rẹ̀ tí Olúwa pa láṣẹ láti sọ; àwọn àlùfáà, àti gbogbo ènìyàn dì í mú, wọ́n sì wí pé, “Kíkú ni ìwọ yóò kú!

Ka pipe ipin Jeremáyà 26

Wo Jeremáyà 26:8 ni o tọ