Jeremáyà 27:18 BMY

18 Tí wọ́n bá jẹ́ wòlíì, tí wọ́n sì ní ọ̀rọ̀ Olúwa, jẹ́ kí wọ́n bẹ Olúwa kí a má ṣe kó ohun èlò tí ó kù ní ilé Júdà àti Jérúsálẹ́mù lọ sí Bábílónì.

Ka pipe ipin Jeremáyà 27

Wo Jeremáyà 27:18 ni o tọ