Jeremáyà 3:15 BMY

15 Lẹ́yìn èyí, èmi ó fún ọ ní àwọn olùṣọ́ àgùntàn láti inú ọkàn mi, tí wọn yóò ṣáájú yín pẹ̀lú òye àti ìmọ̀.

Ka pipe ipin Jeremáyà 3

Wo Jeremáyà 3:15 ni o tọ