Jeremáyà 30:21 BMY

21 Ọ̀kan nínú wọn ni yóò jẹ́ olórí wọn,Ọba wọn yóò dìde láti àárin wọn.Èmi yóò mú un wá sí ọ̀dọ̀ mi, òun yóò sì súnmọ́ mi,nítorí ta ni ẹni náà tí yóò fi ara rẹ̀ jìn láti súnmọ́ mi?

Ka pipe ipin Jeremáyà 30

Wo Jeremáyà 30:21 ni o tọ