Jeremáyà 32:20 BMY

20 O ṣe iṣẹ́ àmì àti iṣẹ́ ìyanu ńlá ní Éjíbítì. O sì ń ṣe é títí di òní ní Ísírẹ́lì àti lára ọmọ ènìyàn tí ó sì ti gba òkìkí tí ó jẹ́ tìrẹ.

Ka pipe ipin Jeremáyà 32

Wo Jeremáyà 32:20 ni o tọ