Jeremáyà 33:7 BMY

7 Èmi ó mú Júdà àti Ísírẹ́lì kúrò nínú ìgbékùn, èmi ó sì tún wọn kọ́ gẹ́gẹ́ bí wọ́n ṣe wà tẹ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Jeremáyà 33

Wo Jeremáyà 33:7 ni o tọ