Jeremáyà 34:18 BMY

18 Èmi ó ṣe àwọn ọkùnrin náà tí ó da májẹ̀mú mi, tí kò tẹ̀lé májẹ̀mú tí wọ́n ti dá níwájú mi bí ẹgbọ̀rọ màlúù tí wọ́n gé sí méjì, tí ó sì kọjá láàrin ìpín méjì náà.

Ka pipe ipin Jeremáyà 34

Wo Jeremáyà 34:18 ni o tọ