Jeremáyà 34:9 BMY

9 Kí oníkálùkù lè jẹ́ kí ẹrúkùnrin àti ẹrúbìnrin tí í ṣe Hébérù lọ lọ́fẹ̀ẹ́, kí ẹnikẹ́ni kí ó má mú ará Júdà arákùnrin rẹ̀ sìn.

Ka pipe ipin Jeremáyà 34

Wo Jeremáyà 34:9 ni o tọ