Jeremáyà 35:2 BMY

2 “Lọ sí ilé àwọn ọmọ Rékábù, kí o sì bá wọn sọ̀rọ̀, kí o sì mú wọn wá sí ilé Olúwa, sí ọ̀kan nínú iyàrá wọ̀n-ọn-nì, kí o sì fún wọn ní ọtí wáìnì mu.”

Ka pipe ipin Jeremáyà 35

Wo Jeremáyà 35:2 ni o tọ