Jeremáyà 36:30 BMY

30 Nítorí náà, báyìí ni Olúwa wí níti Jéhóíákímù Ọba Júdà pé: Òun kì yóò ní ẹni tí yóò jókòó lórí ìtẹ́ Dáfídì, à ó sì sọ òkú rẹ̀ nù fún ooru ní ọ̀sán àti fún òtútù ní òru.

Ka pipe ipin Jeremáyà 36

Wo Jeremáyà 36:30 ni o tọ