20 Ṣùgbọ́n ní báyìí, Olúwa mi Ọba jọ̀wọ́ gbọ́. Jẹ́ kí n mú ẹ̀dùn ọkàn mi tọ̀ ọ́ wá; má ṣe rán mi padà sí ilé Jónátanì akọ̀wé, à fi kí n kú síbẹ̀.”
Ka pipe ipin Jeremáyà 37
Wo Jeremáyà 37:20 ni o tọ