19 Ọba Sedekáyà sọ fún Jeremáyà pé, “Mò ń bẹ̀rù àwọn Júù tó ti sálọ sí ilẹ̀ Bábílónì, nítorí pé àwọn ará Bábílónì lè fà mí lé wọn lọ́wọ́ láti fìyà jẹ mí.”
Ka pipe ipin Jeremáyà 38
Wo Jeremáyà 38:19 ni o tọ