Jeremáyà 4:2 BMY

2 Tí ó bá jẹ́ lóòtọ́ àti òdodo niìwọ búra. Nítòótọ́ bí Olúwa ti wà láàyè,nígbà náà ni orílẹ̀ èdè yóò di alábùkún fúnnípaṣẹ̀ rẹ àti nínú rẹ̀ ni wọn yóò ṣògo.

Ka pipe ipin Jeremáyà 4

Wo Jeremáyà 4:2 ni o tọ