Jeremáyà 40:12 BMY

12 Gbogbo wọn padà wá sí ilẹ̀ Júdà sọ́dọ̀ Jedáláyà ní Mísípà láti orílẹ̀ èdè gbogbo tí a ti lé wọn sí. Wọ́n sì kórè ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọtí wáìnì àti èṣo igi.

Ka pipe ipin Jeremáyà 40

Wo Jeremáyà 40:12 ni o tọ