Jeremáyà 41:11 BMY

11 Nígbà tí Johánánì ọmọkùnrin Kárè àti gbogbo àwọn olórí ogun tí wọ́n wà pẹ̀lú rẹ̀ gbọ́ nípa gbogbo ìpànìyàn náà tí Ísímáẹ́lì ọmọ Nétanáyà ti ṣe.

Ka pipe ipin Jeremáyà 41

Wo Jeremáyà 41:11 ni o tọ