Jeremáyà 41:18 BMY

18 Láti gba àwọn Bábílónì sílẹ̀. Wọ́n bẹ̀rù wọn nítorí wí pé, “Ísímáẹ́lì ọmọ Nétanáyà ti pa Jedaláyà ọmọ Álíkámù èyí tí Ọba Bábílónì ti yàn gẹ́gẹ́ bí i gómínà lórí ilẹ̀ náà.”

Ka pipe ipin Jeremáyà 41

Wo Jeremáyà 41:18 ni o tọ