Jeremáyà 44:18 BMY

18 Ṣùgbọ́n láti ìgbà tí a ti dáwọ́ tùràrí sísun sí ayaba ọrun sílẹ̀ àti láti da ẹbọ ohun mímu fún un, àwa ti ṣaláìní ohun gbogbo, a sì run nípa idà àti nípa ìyàn.”

Ka pipe ipin Jeremáyà 44

Wo Jeremáyà 44:18 ni o tọ