Jeremáyà 46:12 BMY

12 Àwọn orílẹ̀ èdè yóò gbọ́ nípa ìtìjú rẹ,igbe rẹ yóò kún gbogbo ayé.Jagunjagun yóò máa ṣubú lu ara wọn lórí rẹ,àwọn méjèèjì yóò sì dìjọ ṣubú papọ̀.”

Ka pipe ipin Jeremáyà 46

Wo Jeremáyà 46:12 ni o tọ