Jeremáyà 48:1 BMY

1 Nípa Móábù:Báyìí ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun Ọlọ́run Ísírẹ́lì wí:“Ègbé ni fún Nébò nítorí a ó parun.A dójú ti Kíríátaímù, a sì mú un,ojú yóò ti alágbára, a ó sì fọ́nká.

Ka pipe ipin Jeremáyà 48

Wo Jeremáyà 48:1 ni o tọ