Jeremáyà 48:28 BMY

28 Kúrò ní àwọn ìlú rẹ, kí o sì máa gbé láàrin àwọn òkúta,ẹ̀yin tí ó ti ń gbé inú ìlú Móábù.Ẹ dàbí i àdàbà tí ó kọ́ ìtẹ́ rẹ̀sí ẹnu ihò.

Ka pipe ipin Jeremáyà 48

Wo Jeremáyà 48:28 ni o tọ