Jeremáyà 48:32 BMY

32 Mo sunkún fún ọ bí Jásì ṣe sunkúnìwọ àjàrà Síbínà.Ẹ̀ka rẹ tẹ̀ títí dé òkun wọn,Ámónì,ajẹnirun ti kọlu èṣo rẹàti àwọn èṣo àjàrà rẹ.

Ka pipe ipin Jeremáyà 48

Wo Jeremáyà 48:32 ni o tọ