Jeremáyà 5:28 BMY

28 Wọ́n sanra wọ́n sì dán.Ìwà búburú wọn kò sì lópin;wọn kò bẹ̀bẹ̀ fún ẹjọ́ àwọn aláìní baba láti borí rẹ̀.Wọn kò jà fún ẹ̀tọ́ àwọn tálákà.

Ka pipe ipin Jeremáyà 5

Wo Jeremáyà 5:28 ni o tọ