Jeremáyà 5:3 BMY

3 Olúwa, ojú rẹ kò ha wà lára òtítọ́Ìwọ lù wọ́n, kò dùn wọ́n.Ìwọ bá wọn wí, wọ́n kọ̀ láti yípadà.Wọ́n mú ojú wọn le ju òkúta lọ,wọ́n sì kọ̀ láti yípadà.

Ka pipe ipin Jeremáyà 5

Wo Jeremáyà 5:3 ni o tọ