Jeremáyà 52:1 BMY

1 Ṣédékáyà jẹ́ ọmọ ọdún mọ́kànlélógún nígbà tí ó jẹ Ọba. Ọdún mọ́kànlá ló fi jọba ní Jérúsálẹ́mù. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Hámútalì ọmọ Jeremáyà; láti Líbíná ló ti wá.

Ka pipe ipin Jeremáyà 52

Wo Jeremáyà 52:1 ni o tọ