Jeremáyà 52:14 BMY

14 Gbogbo àwọn ọmọ ogun Bábílónì tí wọ́n wà lábẹ́ àṣẹ balógun ìṣọ́ wó gbogbo odi tí ó yí ìlú Jérúsálẹ́mù lulẹ̀.

Ka pipe ipin Jeremáyà 52

Wo Jeremáyà 52:14 ni o tọ