Jeremáyà 9:10 BMY

10 Èmi yóò sì sunkún, pohùnréréẹkún fún àwọn òkè; àti ẹkúnìrora lórí pápá oko ihà wọ̀n-ọn-nì.Nítorí wọ́n di ahoro, wọn kò sìkọjá ní ibẹ̀. A kò sì gbọ́ igbeẹran ọ̀sìn, àwọn ẹyẹ ojú ọ̀runsì ti sá lọ, bẹ́ẹ̀ náà ni àwọn ẹranko sì ti lọ.

Ka pipe ipin Jeremáyà 9

Wo Jeremáyà 9:10 ni o tọ