Jeremáyà 9:19 BMY

19 A gbọ́ igbe ìpohùnréréẹkún ní Síónì:‘Àwa ti ṣègbé tó!A gbọdọ̀ fi ilẹ̀ wa sílẹ̀,nítorí pé àwọn ilé wa ti parun.’ ”

Ka pipe ipin Jeremáyà 9

Wo Jeremáyà 9:19 ni o tọ