Jeremáyà 9:2 BMY

2 Áà! èmi ìbá ní ilé àgbàwọ̀ fúnàwọn arìnrìn-àjò ní ihà kí nba à lè fi àwọn ènìyàn mi sílẹ̀kí n sì lọ kúrò lọ́dọ̀ wọn:nítorí gbogbo wọn jẹ́ pańṣágààjọ aláìsòótọ́ ènìyàn ni wọ́n.

Ka pipe ipin Jeremáyà 9

Wo Jeremáyà 9:2 ni o tọ