Jeremáyà 1:12 BMY

12 Olúwa sì wí fún mi pé, “ó ti rí i bí ó se yẹ, torí pé mo ti ń sọ láti rí i pé ọ̀rọ̀ mi wá sí ìmúsẹ.”

Ka pipe ipin Jeremáyà 1

Wo Jeremáyà 1:12 ni o tọ