Jeremáyà 1:13 BMY

13 Ọ̀rọ̀ Olúwa sì tún tọ̀ mi wá ní ẹ̀ẹ́kèjì pé, “Kí ni o rí?” Mo sì dáhùn pé mo rí ìkòkò gbígbóná, tí ó ń ru láti apá àríwá.

Ka pipe ipin Jeremáyà 1

Wo Jeremáyà 1:13 ni o tọ