Jeremáyà 1:15 BMY

15 Mo sì ti ṣetán láti pe gbogbo àwọn ènìyàn orílẹ̀ èdè àríwá níjà,” ni Olúwa wí.Àwọn Ọba wọn yóò wágbé ìtẹ́ wọn ró ní ojú-ọ̀nà à bá wọléJérúsálẹ́mù. Wọn ó sì dìde sí gbogboàyíká wọn àti sí gbogbo àwọnìlú Júdà.

Ka pipe ipin Jeremáyà 1

Wo Jeremáyà 1:15 ni o tọ